Cook – Sè (transitive)
verb
ex. Mo se ẹwà fún bàbá mi – I cooked beans for my father.
Cook – Dáná (intransitive)
verb
ex. Mi ò lè dáná ní òní – I cannot cook today.
PRONOUNCIATION 👇👇
Cook – Sè (transitive)
verb
ex. Mo se ẹwà fún bàbá mi – I cooked beans for my father.
Cook – Dáná (intransitive)
verb
ex. Mi ò lè dáná ní òní – I cannot cook today.
PRONOUNCIATION 👇👇