Read

Read – Kàwé (intransitive)

verb

ex. Mò ń kàwé – I am reading.

 

Read – Kà (transitive)

verb

ex. Mo fẹ́ràn láti ka iwé ní alẹ́ – I love to read books at night.