Betray – Dà, Dalẹ̀ (transitive)
verb
ex. Ọ̀rẹ́ da ọ̀rẹ́ ẹ̀ – The friend betrayed her friend.
ex. Wọ́n dalẹ̀ wa – They betrayed us.
Betray – Dalẹ̀ (intransitive)
verb
ex. Ẹnikẹni nínú yín ò gbọdọ̀ dalẹ̀ – No one among you must betray.
PRONOUNCIATION 👇👇