Hide

Hide – Gọ, Sá pamọ́, Fara pamọ́

verb

ex. Àwọn ọmọ gọ sínú ilé – The kids hide in the house.

ex. Mò ń sá pamọ́ fún ọ̀rẹ́ mi – I am hiding from my friend.

ex. Mo ní láti fara pamọ́ – I need to hide.

PRONOUNCIATION 👇👇