Meet – Bá, Pàdé
verb
ex. Mo máa ba yín ní ilé – I will meet you at home.
ex. Ṣé ẹ lè pàdé mi ní pápákọ̀-òfuurufú – Can you meet me at the airport?
PRONOUNCIATION 👇👇