Pass

Pass – Yege (exams)

verb

ex. A yege ìdánwò wa – We passed our examinations.

 

Pass – Kọjá (Permission to move)

verb

ex. Ẹ jẹ kí n kọja – Let me pass.

PRONOUNCIATION 👇👇