Peel – Bó, Bẹ́, Hó
verb
ex. Mò ń bó àlùbọ́sà – I am peeling the onions.
ex. Ọláyẹmí ń bẹ iṣu – Olayemi is peeling the yam.
ex. Bá mi hó ọsàn – Help me to peel the orange.
PRONOUNCIATION 👇👇