Sing

Sing – Kọ (transitive)

verb

ex. Mò ń kọ Fújì – I am singing Fuji.

PRONOUNCIATION 👇👇

 

Sing – Kọrin (intransitive)

ex. Ẹyẹ ń kọrin – The bird is singing.

PRONOUNCIATION 👇👇